Jesu Akọni mi/Jesus My Hero: Yoruba Bilingual Translation
Description
Lẹyin Halloween ni ọdun to kọja, ọmọ mi Ivan, ọmọ ọdun meji ṣaa deede bẹẹrẹ si ni bẹru ẹmi adẹrubaniyan nigbati o ba wa ninu okunkun. O bẹẹrẹ si ni isoro lati sun laalẹ. Yio ji ni ọpọlọpọ igba- pẹlu omi ẹkun - yio maa wipe: "Adẹrubaniyan ...Ẹru n bami..."Nitori eleyi, emi ati ọkọ mi gbiyanju ni gbogbo ọna lati ṣalaye nipa Jesus Kiristi fun n sugbọn ko ye e. Nitoribẹ, mo pinnu lati ṣe iwe awọn ọmọde, eyi ti o mu u rọrun lati mọ ẹniti Jesu jẹ. Iwe naa ni a pe ni "Jesu Akọni Mi" nitoripe, O ku lori agbelebu fun ẹṣẹ wa ti O si GBA WA LA lọwọ iparun ayeraye. Oun ni akọni didara julọ Iwe naa jẹ abala marun (oju ewe mẹwa) nitoribẹ o se e ka ni alaalẹ fun awọn ọmọ wa. Ati wipe nigbati wọn ba dagba to o, wọn le e ka fun ra a wọn Jesu Akọni Mi sọrọ nipa agbara Jesu lori ẹẹru, aisan, ijaya ati awọn iwulo ojoojumọ wa (igbesi aye ile-iwe) - eyiti o niise pẹlu awọn ọdọ wa (ati awọn ti o dagba diẹ) ni ode oni ati ọjọ iwaju.After Halloween last year, my 2-year-old son, Ivan, developed a sudden fear of monsters and being in the dark. He started struggling to sleep. He would often wake up - in tears - saying: "monsters... I'm scared..." Following that, my husband and I regularly try to explain who Jesus Christ is to him but he doesn't understand. So I decided to make a children book, that simplifies who Jesus is. The book is called "Jesus My Hero" because he died on the cross for our sins and SAVED us from eternal damnation. He is the ultimate superhero The book is only 5 spreads (10 pages) long, so it can be read every night to our little ones. And when they're old enough, they can read it for themselves Jesus My Hero addresses Jesus' power in the matters of fear, sickness, anxiety and general everyday needs (i.e school life) - all which affect our young (and older) children in this day and age.Product Details
BISAC Categories:
Earn by promoting books
Earn money by sharing your favorite books through our Affiliate program.
About the Author
Michael S. Williams is president and CEO of Market Compass, LLC, which specializes in financial education for investors and traders online, via the Internet, and through the PCX Institute. Williams has been an options market maker on the Pacific Exchange (PCX) for nearly a decade. He is a frequent speaker at conferences around the country including the TSAA annual conference, the Options Industry Council seminars, and The Money Show.
Amy S. Hoffman is a founder and vice-president of Market Compass, LLC. She has been an options market maker on the Pacific Exchange (PCX) trading for hedge funds and as an independent market maker. Hoffman's financial career began in 1989 as a compliance officer and in-house trader for a large commodities firm. She is currently an instructor for the PCX Institute and Options Industry Council.